Sekaráyà 11:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ṣí àwọn ìlẹ̀kùn rẹ sílẹ̀, ìwọ Lébánónì,kí iná bá lè jẹ igi Kédárì rẹ run,

2. Pohùnréré-ẹkún, igi fírì;nítorí igi Kédárì ṣubú,nítorí tí a ba àwọn igi tí o lógo jẹ́:ṣunkún kíkorò ẹ̀yin igi óákù tí Básánì,nítorí gé igbó àjàrà lulẹ̀.

Sekaráyà 11