Sekaráyà 10:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi ó sì mú wọn ní agbára nínú Olúwa;wọn ó sì rìn sókè rìn sódò ni orúkọ rẹ̀,”ni Olúwa wí.

Sekaráyà 10

Sekaráyà 10:11-12