Sefanáyà 3:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn wòlíì rẹ̀ gbéraga,wọ́n sì jẹ́ alárékérekè ènìyàn.Àwọn àlùfáà rẹ̀ ti ba ibi mímọ́ jẹ́,wọ́n sì rú òfin.

Sefanáyà 3

Sefanáyà 3:1-7