ọjọ́ náà yóò jẹ́ ọjọ́ ìbínú,ọjọ́ ìrora àti ìpọ́njú,ọjọ́ òfò àti idà ọjọ́ ìdahoroọjọ́ òkùnkùn àti ìtẹ̀ba,ọjọ́ kuru àti òkùnkùn biribiri,