Sefanáyà 1:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ọjọ́ ńlá Olúwa kù sí dẹ̀dẹ̀,ó kù sí dẹ̀dẹ̀ ó sì ń yára bọ̀kánkán. Ẹ tẹ́tí sílẹ̀, ohùn ẹkúnàwọn alágbára ní ọjọ́ Olúwa yóò korò púpọ̀,

Sefanáyà 1

Sefanáyà 1:13-17