Sáàmù 99:8-9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

8. Olúwa Ọlọ́run wa, ó dá wọn lóhùn;ó jẹ́ Ọlọ́run tí ó ń dáríjìn àwọn ọmọ Ísírẹ́lììwọ tí ó ń fi ìyà àìṣedédé wọn jẹ wọ́n

9. Gbígbé ga ni Olúwa Ọlọ́run wakí a sìn ín ní òkè mímọ́ Rẹ̀nítorí Olúwa Ọlọ́run wa jẹ́ mímọ́.

Sáàmù 99