Sáàmù 99:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa Ọlọ́run wa, ó dá wọn lóhùn;ó jẹ́ Ọlọ́run tí ó ń dáríjìn àwọn ọmọ Ísírẹ́lììwọ tí ó ń fi ìyà àìṣedédé wọn jẹ wọ́n

Sáàmù 99

Sáàmù 99:1-9