Sáàmù 99:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sọ̀rọ̀ sí wọn nínú ọ̀wọ́n àwọsánmọ̀,wọ́n pa ẹrí Rẹ̀ mọ́ àti ìlànà tí ó fún wọn.

Sáàmù 99

Sáàmù 99:1-9