Sáàmù 98:5-9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

5. Ẹ fi dùùrù kọrin sí Olúwa, pẹ̀lú dùùrù àti ìró ohùn orin mímọ́,

6. Pẹ̀lú ìpè àti fèrèẹ hó fún ayọ̀ níwájú Olúwa Ọba.

7. Jẹ́ kí òkun kí o hó pẹ̀lú gbogboohun tí ó wà nínú Rẹ̀,Gbogbo ayé àti gbogbo àwọn tí ń gbé inú Rẹ̀.

8. Ẹ jẹ́ kí odo kí ó sápẹ́,ẹ jẹ́ kí òkè kí o kọrin pẹ̀lú ayọ̀;

9. Ẹ jẹ́ kí wọn kọrin níwájú OlúwaNítorí tí yóò wá ṣè dájọ́ ayébẹ́ẹ̀ ni yóò ṣe ìdájọ́ àwọn orílẹ̀-èdè nínú òdodoàti àwọn ènìyàn ní àìṣègbè pẹ̀lú.

Sáàmù 98