Sáàmù 98:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jẹ́ kí òkun kí o hó pẹ̀lú gbogboohun tí ó wà nínú Rẹ̀,Gbogbo ayé àti gbogbo àwọn tí ń gbé inú Rẹ̀.

Sáàmù 98

Sáàmù 98:1-9