Sáàmù 98:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ẹ kọrin túntún sí Olúwa,nítorí tí ó ṣe ohun ìyanu;ọwọ́ ọ̀tún Rẹ̀ àti apa mímọ́ Rẹ̀o ṣe iṣẹ́ ìgbàlà fún un

2. Olúwa ti sọ ìgbàlà Rẹ̀ di mímọ̀o fí òdodo Rẹ̀ han àwọn orílẹ̀ èdè.

3. Ó rántí ìfẹ́ Rẹ̀ àti òtítọ́ Rẹ̀ fún àwọn ará ilé Ísírẹ́lì;gbogbo òpin ayé ni ó ti ríiṣẹ́ ìgbàlà Ọlọ́run wa.

Sáàmù 98