Sáàmù 98:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó rántí ìfẹ́ Rẹ̀ àti òtítọ́ Rẹ̀ fún àwọn ará ilé Ísírẹ́lì;gbogbo òpin ayé ni ó ti ríiṣẹ́ ìgbàlà Ọlọ́run wa.

Sáàmù 98

Sáàmù 98:1-9