Sáàmù 97:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo àwọn tí ń sin òrìṣà ni ojú yóò ti,àwọn ti n fi ère ṣe àfẹ́rí ara wọnẸsìn ín, ẹ̀yin òrìṣà;

Sáàmù 97

Sáàmù 97:5-12