Sáàmù 94:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbé ara Rẹ sókè, ìwọ onídàájọ́ ayé;san ẹ̀san fún agbéragaohun tí ó yẹ wọ́n.

Sáàmù 94

Sáàmù 94:1-3