Sáàmù 94:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Olúwa Ọlọ́run ẹni tí ń gbẹ̀san,Ọlọ́run ẹni tí ń gbẹ̀san.

2. Gbé ara Rẹ sókè, ìwọ onídàájọ́ ayé;san ẹ̀san fún agbéragaohun tí ó yẹ wọ́n.

3. Báwo ní yóò ti pẹ́ tó, Olúwatí àwọn ẹni búburúyóò kọ orin ayọ̀?

Sáàmù 94