Sáàmù 91:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun yóò pè mí, èmi yóò sì dáa lóhùn;èmi yóò wà pẹ̀lú Rẹ̀ nínú ipọ́nju,èmi yóò gbà á, èmi yóò sì bu ọlá fún un

Sáàmù 91

Sáàmù 91:13-16