Sáàmù 91:1-4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ẹni tí ó gbé ibi ìkọ̀kọ̀ ọ̀gá ògoni yóò sinmi ní ibi òjìji Olódùmarè.

2. Èmi yóò sọ nípa ti Olúwa pé,“Òun ní ààbò àti odi mi,Ọlọ́run mi, ẹni tí èmi gbẹ́kẹ̀lé”.

3. Ní tòótọ́ òun yóò gbà mí nínúìdẹkùn àwọn pẹyẹ pẹyẹàti nínú àjàkálẹ̀-àrùn búburú.

4. Òun yóò fi ìyẹ́ Rẹ̀ bò mí,àti ni abẹ́ ìyẹ́ Rẹ̀ ni èmi yóò ti rí ààbò;òtítọ́ Rẹ̀ ni yóò ṣe ààbò àti odi mi.

Sáàmù 91