Sáàmù 91:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun yóò fi ìyẹ́ Rẹ̀ bò mí,àti ni abẹ́ ìyẹ́ Rẹ̀ ni èmi yóò ti rí ààbò;òtítọ́ Rẹ̀ ni yóò ṣe ààbò àti odi mi.

Sáàmù 91

Sáàmù 91:1-12