Sáàmù 89:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tìrẹ ní àwọn ọ̀run, ayé pẹ̀lú jẹ tìrẹ:ayé àti ohun gbogbo tí ó wà nínú Rẹ̀:ìwọ ti gbé wọn kalẹ̀.

Sáàmù 89

Sáàmù 89:9-12