Sáàmù 89:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ ni o ti ya Ráhábù pẹ́rẹpẹ̀rẹbí ẹni tí a pa;ìwọ ti fi apá ọwọ́ agbára Rẹtú àwọn ọ̀tá Rẹ ká.

Sáàmù 89

Sáàmù 89:1-13