Sáàmù 87:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítòótọ́, tí Síónì ni a ó sọ,“Eléyìí àti eléyì í ni a bí nínú Rẹ̀,àti Ọlọ́run Ọ̀gá ògo ni yóò fìdí Rẹ̀ múlẹ̀.”

Sáàmù 87

Sáàmù 87:1-6