Sáàmù 87:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Èmi ó dárúkọ Rákábù àti Bábílónìláàrin àwọn tí ó jẹ́wọ́ mi:Fílístínì pẹ̀lú, àti Tirẹ, pẹ̀lú Kúṣìyóò sọ pé, èyí ni a bí ni Síónì.”

Sáàmù 87

Sáàmù 87:1-7