Sáàmù 85:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi ó gbọ́ ohun tí Olúwa Ọlọ́run yóò wí;ó ṣèlérí àlàáfíà fún àwọn ènìyàn Rẹ̀, àní ẹni mímọ́ Rẹ̀:Ṣùgbọ́n má ṣe jẹ́ kí wọn padà sí àìmòye.

Sáàmù 85

Sáàmù 85:7-13