Sáàmù 83:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wo bí àwọn ọ̀tá Rẹ ti ń rọ́kẹ̀kẹ̀ lọ,bi àwọn ọ̀tá Rẹ ti ń gbé ohùn wọn sókè.

Sáàmù 83

Sáàmù 83:1-5