Sáàmù 82:5-8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

5. “Wọn kò mọ̀ ohunkankan,wọn kò lóye ohunkankan.Wọn ń rìn kiri nínú òkùnkùn;a ni gbogbo ìpínlẹ̀ ayé.

6. “Mo wí pé, ‘Ẹyin ní “Ọlọ́run òrìṣà”;ẹ̀yin ní gbogbo ọmọ ọ̀gá ògo jùlọ.’

7. Ṣùgbọ́n ẹ̀yin o kú bí ènìyàn lásán;ẹ̀yin ó ṣubú bí ọ̀kan nínú ọmọ aládé.”

8. Dìde Ọlọ́run ṣe ìdájọ́ ayé,nítorí gbogbo orílẹ̀ èdè ni ìní Rẹ.

Sáàmù 82