Sáàmù 82:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Wọn kò mọ̀ ohunkankan,wọn kò lóye ohunkankan.Wọn ń rìn kiri nínú òkùnkùn;a ni gbogbo ìpínlẹ̀ ayé.

Sáàmù 82

Sáàmù 82:3-8