Sáàmù 81:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Kọrin sókè sí Ọlọ́run agbára waẸ hó ìhó ayọ̀ sí Ọlọ́run Jákọ́bù!

2. Ẹ mú orin mímọ́, kí ẹ sì mú ìlù wátẹ dùùrù dídùn pẹ̀lú ohun èlò orin mímọ́.

Sáàmù 81