Sáàmù 80:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tún wa yípadà, Olúwa Ọlọ́run;kí ojú Rẹ̀ kí o tan ìmọ́lẹ̀ sí wa,kí á ba à lè gbà wá là.

Sáàmù 80

Sáàmù 80:12-19