Sáàmù 8:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

kí ni ènìyàn tí ìwọ ń rò nípa Rẹ̀,ọmọ ènìyàn tí ìwọ ń ṣe ìtọ́jú Rẹ̀?

Sáàmù 8

Sáàmù 8:1-6