Sáàmù 78:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwa kí yóò pa wọ́n mọ́kúrò lọ́dọ̀ àwọn ọmọ,ní fífí ìyìn Olúwa, àti ipa Rẹ̀àti iṣẹ́ ìyanu tó ti ṣe hànfún ìran tí ń bọ̀.

Sáàmù 78

Sáàmù 78:1-5