Sáàmù 75:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A fi ìyìn fún ọ, Ọlọ́run,a yìn ọ́, nítorí orúkọ Rẹ̀ súnmọ́ tòsí;àwọn ènìyàn ń sọ ti ìyanu Rẹ.

Sáàmù 75

Sáàmù 75:1-4