Sáàmù 74:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Má ṣe fi ẹ̀mí àdàbà Rẹ fún ẹranko ìgbẹ́ búburú;Má ṣe gbàgbé ẹ̀mí àwọn ènìyàn Rẹ tí a ń pọ́n lójú títí láé.

Sáàmù 74

Sáàmù 74:18-23