Sáàmù 73:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìgbéraga ni ọ̀ṣọ́ ọrùn wọn;ìwà ìpá bò wọ́n mọ́lẹ̀ bí aṣọ.

Sáàmù 73

Sáàmù 73:1-11