Sáàmù 73:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní gbogbo ọjọ́ ni a ń yọ mí lẹ́nu;a sì ń jẹ mí níyà ní gbogbo òwúrọ̀.

Sáàmù 73

Sáàmù 73:12-20