Sáàmù 73:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítòótọ́ nínú asán ni mo pa ọkàn mi mọ́;nínú asán ni mo wẹ ọwọ́ mi ní àìlẹ́sẹ̀.

Sáàmù 73

Sáàmù 73:5-19