Sáàmù 72:1-4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Fi ìdájọ́ fún àwọn ọba, Ọlọ́run,ọmọ aládé ni ìwọ fi òdodo Rẹ fún

2. Yóò ṣe ìdàjọ́ àwọn ènìyàn Rẹ̀ pẹ̀lú òdodoyóò sì máa fi ẹ̀tọ́ ṣe ìdájọ́ àwọn talákà Rẹ

3. Àwọn òkè ńlá yóò máa mú àlàáfíà fún àwọn ènìyànàti òkè kékèké nípa òdodo

4. Yóò dábò bò àwọn tí a pọ́n lójú láàrin àwọn ènìyànyóò gba àwọn ọmọ aláìní;yóò sì fa àwọn aninilára ya.

Sáàmù 72