Sáàmù 71:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ahọ́n mí yóò sọ ti òdodo Rẹ ní gbogbo ọjọ́,fún àwọn tí ó fẹ́ pa mí láraa sì dójúti àwọn tí ń wá ìdààmú mi.

Sáàmù 71

Sáàmù 71:19-24