Sáàmù 71:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbà mí, Ọlọ́run mi, lọ́wọ́ àwọn olùṣe búburú,ní ọwọ́ aláìsòdodo àti ìkà ọkùnrin.

Sáàmù 71

Sáàmù 71:1-7