Sáàmù 71:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jẹ́ àpáta ààbò mi,nibi tí èmi lè máa lọpa àṣẹ láti gbà mí,nítorí ìwọ ni àpáta àti asà mi.

Sáàmù 71

Sáàmù 71:1-8