Sáàmù 70:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí àwọn tí ń wá ọkàn mikí a dojú tì wọ́n, kí wọn sì dààmú;kí àwọn tó ń wá ìparun miyí ẹ̀yìn padà nínú ìtìjú.

Sáàmù 70

Sáàmù 70:1-3