Sáàmù 7:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dìde, Olúwa, nínú ìbínú Rẹ;dìde lòdì sí ìrunú àwọn ọ̀ta mi.Jí, Ọlọ́run mi; kéde òdodo.

Sáàmù 7

Sáàmù 7:1-11