Sáàmù 7:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà jẹ́ kí ọ̀ta mi le mi kí wọn sì mú mi;jẹ́ kí òun kí ó tẹ ẹ̀mí mi mọ́lẹ̀kí wọn sì mú mi sùn nínú eruku. Sela

Sáàmù 7

Sáàmù 7:1-15