Sáàmù 69:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Má ṣe pa ojú Rẹ mọ́ fún ọmọ ọ̀dọ̀ Rẹ:yára dá mi lóhùn, nítorí mo wà nínú ìpọ́njú.

Sáàmù 69

Sáàmù 69:8-20