Sáàmù 65:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ bẹ ayé wò, o sì bomirin;ìwọ mú ní ọ̀rọ̀ púpọ̀.Ọ̀dọ̀ Ọlọ́run kún fún omiláti pèsè ọkàn fún àwọn ènìyàn,nítorí ibẹ̀ ní ìwọ ti yàn án.

Sáàmù 65

Sáàmù 65:6-11