Sáàmù 65:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Agbo ẹran ni a fi wọ pápá tútù náà, ni asọ; àfonífojì ni a fi ọkà bò mọ́lẹ̀,wọn hó fún ayọ̀, wọn ń kọrin pẹ̀lú.

Sáàmù 65

Sáàmù 65:10-13