Sáàmù 65:10-13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

10. Ìwọ fi ìrinmi sí aporo Rẹìwọ tẹ́ ògúlùtù Rẹ;ìwọ fi òjò mú ilẹ̀ Rẹ rọ̀o sì bùkún ọ̀gbìn Rẹ.

11. Iwọ fi oore Rẹ de ọdún ni adé,ọ̀rá ń kan ni ipa-ọ̀nà Rẹ

12. Pápá-tútù ni ihà ń kán: àwọn òkè kékèké fi ayọ̀ di ara wọn ni àmùrè.

13. Agbo ẹran ni a fi wọ pápá tútù náà, ni asọ; àfonífojì ni a fi ọkà bò mọ́lẹ̀,wọn hó fún ayọ̀, wọn ń kọrin pẹ̀lú.

Sáàmù 65