Sáàmù 63:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọlọ́run, ìwọ ni Ọlọ́run mi,nígbà gbogbo ní mo ń ṣàfẹ́rí Rẹóùngbẹ́ Rẹ ń gbẹ ọkàn miara mi fà sí ọ,ní ilẹ̀ gbígbẹ àti ilẹ̀ ti ń ṣàárẹ̀níbi tí kò sí omi

Sáàmù 63

Sáàmù 63:1-11