Sáàmù 62:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pẹ̀lúpẹ̀lú, Olúwa, tirẹ ni àánúnitorí ti iwọ san án fun olúkúlùkù ènìyàn gẹ́gẹ́ bi iṣẹ́ Rẹ̀.

Sáàmù 62

Sáàmù 62:2-12