Sáàmù 62:6-8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

6. Òun nìkan ní àpáta àti ìgbàlà mi;Òun ni ààbò mi, a kí yóò sí mi nípò.

7. Ìgbàlà mi àti ògo mí dúró nínú Ọlọ́run;Òun ní àpáta ńlá mi, àti ààbò mi.

8. Gbẹ́kẹ̀lé ní gbogbo ìgbà, ẹ̀yin ènìyàn;tú ọkàn Rẹ̀ jáde sí i,nítorí Ọlọ́run ní ààbò wa.

Sáàmù 62