Sáàmù 59:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ agbára mi, èmi ó kọrin ìyìn sí ọ;ìwọ, Ọlọ́run, ààbò mi, Ọlọ́run ìfẹ́ mi.

Sáàmù 59

Sáàmù 59:11-17